ONISHEGUN (feat. Gbenga Akinfenwa & Mr Wols) [Live]
Abiola TAG
Onishegun nla wa nihin
Jesu abanidaro
Oro Re mu ni l'ara da
Agbo ohun ti Jesu
Iro didun l'orin Seraf
Oruko didn li ahon
Orin t'o dun julo ni
Jesu Jesu Jesu
Onishegun nla wa nihin
Jesu abanidaro
Oro Re mu ni l'ara da
Agbo ohun ti Jesu
Iro didun l'orin Seraf
Oruko didn li ahon
Orin t'o dun julo ni
Jesu Jesu Jesu