Ride On [Album]

Monique Temitope Fabiyi

Agbára Olórun mbe níbí
The Power of God is here
Èmí Olórun mbe níbí
The Spirit of God is here

Momòpé bímobá képè é Óma foùn
Momòpé bímobá képè é Á sògo
I kno-o-o-w that the Spirit of God will cause an overflow

Ride on ride on ride on
Èmí oooo
Ride on ride on ride on ri-i-i-de on

Agbara oo aaa
Agbára Olórun mbe níbí
The Power of God is here the Power of God is here
Èmí ooooo Èmí Olórun mbe níbí
The Spirit of God yeah the Spirit of God is here

Momòpé bímobá képè é Óma foùn Óma foùn
Momòpé bímobá képè é Á sògo
I kn-o-o-o-w I know that the Spirit of God the Spirit of God will cause an overflow

Ride on ride on ride on
Èmí oooo
Ride on ride on ride on ri-i-i-de on

Let my ears belong to You
So all I hear is You
Let my heart belong to You let my heart belong to You
Ehhyy so all I do is You
Shield me from the power of sin aah aah aah aah
Let them gat nothing on me
Holy Spirit
Gbàmí tán ehh ehh ehh ehh

Momòpé bímobá képè é Óma foùn
Momòpé bímobá képè é Á sògo
I know that the Spirit of God will cause an overflow

Ride on ride on ride on
Èmí oooo
Ride on ride on ride on

Agbára Olórun mbe láyé mi
Agbára tóh borí ohun gbogbo Agbára Olórun mbe ni bi
Who art thou oh mountain níwájú Oba Ayeraye Agbára Olórun mbe ni bi
Olúwa tóh pò nípá àti agbára
Òkan soso òrò tí nso gbogbo òrò Agbára Olórun mbe ni bi
Òrò gbénú omi adágún
Òrò gbénú omi òkun ru Agbára Olórun mbe ni bi
Òrò tin kan O' lomo nise
Ìjìnlè nlá Atófaratì bí òkè
Momòpé bímobá képè é Óma foùn
Mopá tàsetàse L’órúko Jesu Kristì
Egbé oríiyín sókè èyin enu ònà kí asì gbé e yín sókè èyin ilèkùn ayérayé momòpé bímobá képè é Á sògo
Kí Oba ògo kíó wolé wá I know that the Spirit of God
Àkóbí nú àwon òkú will cause an overflow
Odó àgùntàn tíó fèmí rè lé’lè fún wa ride on ride on
Olùdámòràn ride on
Igi òkìkí ride on àpáta aìí dìgbòlù ride on òkè táò l’esí ride on
Ojiji ati Imole

Músicas mais populares de Monique

Outros artistas de Schlager music