Alashe L'Aiye [Album]

king Sunny Ade

Alashe laiye Alashe lorun
Baba Baba Baba ku ise
Alashe laiye Alashe lorun
Baba Baba Baba ku ise

Iyanu tose laiye mi lo jo mi loju
Mo dupe ore ana
Mo tun dupe ore oni
Ore ré ti kin ye igbekele mi
Iyi ogo ye e o
Bo n ti se mi ré pelu mi Ko ma se

Emi o yi n Oluwa
Oba rere to n segbe mi
Emi o yi n Oluwa
Oba rere to n segbe mi

Ma foun mi yin Baba mi
Ma fi jo mi n yi n
Ma foun mi yin Baba mi
Ma fi jo mi n yi n

Ma jo roin roin
Ma jo roin roin
Ma fi koto ori ile majo roin roin
Ma jo roin roin
Ma jo roin roin
Ma fi koto ori ile majo roin roin

Opa ki n fa gbo gbo
Shekere Oba ni le Oluwa
Shere ni o maa lo
Opa ki n fa gbo gbo
Shekere Oba ni le Oluwa
Shere ni o maa lo

Oluwa lo pe mi Emi nko lo pe ra mi
Ko le baaje
Ko le baaje ooo
E wi ki n gbo
Ko le baaje
Ko le baaje ooo

Músicas mais populares de King Sunny Ade

Outros artistas de African music