Tori (Because)
Tori o
Tori o
Tori mo ni o ni baba
Mi o ni lati beru
Tori o
Tori o
Tori mo ni o ni baba
Ireti n'be fun mi
Solo 1:
Nigbati mo su bu
Nigbati mo so nu
Iwo mu mi pada wale (Wa so do re Oluwa)
Oluwa lo odi mi
Igbega abo mi
Ninu re ojo ola mi (Ada ra)
Play Chorus:
Ni Tori eyi
Mi o ni lati beru mo o
No Tori eyi
Mi o ni lati fo ya mo
Chorus:
Tori o
Tori o
Tori mo ni o ni baba
Mi o ni lati beru
Tori o
Tori o
Tori mo ni o ni baba
Ireti n'be fun mi
Solo 2:
Aya mi o ja
Eru o bami mo
Olu n'be leyin mi
O duro gboyin-gboyin
Iberu ko si fu mi o
You are always by my side
I don't have to fear
Play Chorus:
Ni Tori eyi
Mi o ni lati beru mo o
No Tori eyi
Mi o ni lati fo ya mo
Chorus:
Tori o
Tori o
Tori mo ni o ni baba
Mi o ni lati beru
Tori o
Tori o
Tori mo ni o ni baba
Ireti n'be fun mi
Bridge:
Mo ni o ni baba (Mo ni o ni baba)
Chant
Mo ni o ni baba (Mo ni o ni baba)
Mo ni o ni baba (Mo ni o ni baba)
O Kan mi yin Oluwa
Mi o ni lati beru (Mo ni o ni baba)
O Kan mi yin Oluwa
I don't have to fear no more(Mo ni o ni baba)
I have you as my Lord and my king(Mo ni o ni baba)