Aleluya Meje

Brymo

Aleluya méje méje
Oselu pé jọ f'ọjọ méje
Won fẹ tó'lú lójó méje
Gbogbo iṣẹlẹ korin kese

Aleluya méje méje
Awon ojelu ferege
Won l'awọn ọmọ yepa tún ti de
Wọn fẹ dá'lúrú m'èrè lè

Aleluya méje méje
Akonileru wọn tún ti de
Wọn fẹ sọ bo'ṣè má máa gbe
Iwo f'okun s'ọrun òun ṣiṣẹ agbe

Gbogbo iṣẹlẹ korin kese
Wọn l'awọn omidan ló m'àiyé lè
Wọn fe jeka wọn fẹ roso
Oko ló m'àiyé ọkùnrin lè

B'oko waju si e k'ota
Bo ba k'eyin si e k'ota
Bo ba kú 'wọ nìkàn se ohun olese
Ma gbàgbé ibí o ti n'babọ' o

B'oko waju si e k'ota
Bo ba k'ẹyin si e k'ota
Bo ba kuwo nìkàn se ohun olese
Ma gbàgbé ibí o ti n'babọ' o

Aleluya méje méje (Arere epa epa)
Adaleru won tun ti de (Arere epa epa)
Kofe k'ọmọ o mo bàbá rẹ (Arere epa epa)
Kofe k'ọkọ o gbọ t'àyà rẹ (Arere epa epa)

Gbogbo iṣẹlẹ korin-kese (Arere epa epa)
Won l'awọn omidan lomayele (Arere epa epa)
Wọn fe jeka wọn fẹ roso (Arere epa epa)
Oko ló m'àiyé ọkùnrin lè (Arere epa epa)
Eh ya yah ya

Curiosidades sobre a música Aleluya Meje de Brymo

Quando a música “Aleluya Meje” foi lançada por Brymo?
A música Aleluya Meje foi lançada em 2021, no álbum “Ésan”.

Músicas mais populares de Brymo

Outros artistas de