Eyé Àdabá

BUKOLA ELEMIDE, COBHAMS EMMANUEL ASUQUO

Ojumo ti mo ojumo ti momi
Ni ile yi o
Ojumo ti mo mo ri re o

Ojumo ti mo ojumo ti momi
Ni ile yi o
Ojumo ti mo mo ri re o

Eye adaba eye adaba
Eye adaba ti fo lokeloke
Wa a balemi o
Ojumo ti mo mo ri re o

Ojumo ti mo ojumo ti momi
Ni ile yi o
Ojumo ti mo mo ri re o

Ojumo ti mo ojumo ti momi
Ni ile yi o
Ojumo ti mo mo ri re o o ya

Eye adaba eye adaba eye e e e
Eye adaba ti fo lokeloke
Wa a balemi o o o
Ojumo ti mo mo ri re o o ya

Eye adaba eye adaba eye e e e
Eye adaba ti fo o n fo n fo
Wa a ba lemi o
Ojumo ti mo mo ri re o

E wi kin gbo se
Eye adaba eye eee
Eye adaba ti fo lokeloke loke ode orun
Wa ba le mi o o
Ojumo ti mo mo ri re o

O o o o ye e
Eye adaba eye eye oo
Eye adaba ti fo n on fo o nfo
Wa bale mi oo
Ojumo ti mo mo ri re o

O o oo oo ooo
O o oo o
Ewi kin gbo se
O o oo o
Aah o o o oo o
Oo mo ri re o
O o o o ooo o
Mori re o
Ire ire ire ooo

O o o o o
Mori re o
Eye adaba eye adaba
Eye ti fo lokeloke ode orun
Wa ba lemi o
Ojumo ti mo mo ri re o

Curiosidades sobre a música Eyé Àdabá de Aṣa

Em quais álbuns a música “Eyé Àdabá” foi lançada por Aṣa?
Aṣa lançou a música nos álbums “Asa” em 2007, “Aṣa” em 2007 e “Live In Paris” em 2009.
De quem é a composição da música “Eyé Àdabá” de Aṣa?
A música “Eyé Àdabá” de Aṣa foi composta por BUKOLA ELEMIDE, COBHAMS EMMANUEL ASUQUO.

Músicas mais populares de Aṣa

Outros artistas de Reggae music